Yoruba/Numbers
1- Oókan
2- Eéjì
3 - Ẹẹ́ta
4 - Ẹẹ́rin
5- Aárùn-ún
6- Ẹẹ́fà
7- Eéje
8 - Ẹẹ́jọ
9 - Ẹẹ́sàán
10- Ẹẹ́wàá
11 - Ọọ́kànlá
12- Eéjìlá
13- Ẹẹ́tàlá
14 - Ẹ́rìnlá
15 - Márùndínlógún/Mẹ́ẹ̀ẹ́dógún
16 - Ẹ́rìndínlógún
17 - Ẹ́tàdínlógún
18 - Éjìdínlógún
19 - Ọ́kàndínlógún
20 - Ogún
21 - Ọ́kànlélógún
22 - Méjìlélógún
23 - Mẹ́tàlélógún
24 - Mẹ́rìnlélógún
25 - Márùndínlọ́gbọ̀n
26 - Mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n
27 - Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n
28 - Méjìdínlọ́gbọ̀n
29 - Ọ̀kándínlọ́gbọ̀n
30 - Ọgbọ̀n
40 - Ogójì
50 - Àádọ́ta
60 - Ọgọ́ta
70 - Àádọ́rin
80 - Ọgọ́rin
90 - Àádọ́rùn-ún
100 - Ọgọ́rùn-ún
101 - Ọ́kàn lé lọ́gọ́rùn-ún
102 - Méjì lé lọ́gọ́rùn-ún
103 - Mẹ́tà lé lọ́gọ́rùn-ún
104 - Mẹ́rìn lé lọ́gọ́rùn-ún
105 - Márùn dín láàádọ́fà
110 - Àádọ́fà
120 - Ọgọ́fà
130 - Àádọ́je
140 - Ọgọ́je
150 - Àádọ́jọ
160 - Ọgọ́jọ
170 - Àádọ́sàn-án
180 - Ọgọ́sàn-án
190 - Àádọ́wàá
200 - Igba
300 - Ọ̀ọ́dúnrún
400 - Irinwó
500 - Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta
600 - Ẹgbẹ̀ta
700 - Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin
800 - Ẹgbẹ̀rin
900 - Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún
1,000 - Ẹgbẹ̀rún
2,000 - Ẹgbẹ̀wá/Ẹgbàá
2,500 - Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀tàlá
3,000 - Ẹgbẹ̀ẹ̀ẹ́dógún
4,000 - Ẹgbààjì
5,000 - Ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta
6,000 - Ẹgbàáta
7,000 - Ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin
8,000 - Ẹgbàárin
9,000 - Ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrún
10,000 - Ẹgbààrún
20,000 - Ọ̀kẹ́
50,000 - Ọ̀kẹ́ méjì (àti) ààbọ̀
100,000 - Ọ̀kẹ́ márùn-ún
1,000,000 - Àádọ́ta ọ̀kẹ́ / egberun egberun / egbelegbe
10,000,000 - egbelegbe mewaa
100,000,000 - egbelegbe ogorun
1,000,000,000 - egbelegbéji
10,000,000,000 - egbelegbéta
100,000,000,000 - egbelegbérin
1,000,000,000,000 - egbelegbarun
10,000,000,000,000 - egbelegbéfà
100,000,000,000,000 - egbelegbèje
1,000,000,000,000,000 - egbelegbéjo
For more information on Yorùbá numbers, visit Wikipedia's page on Yorùbá Numerals or the website Yoruba Numeral.