ṣukuṣuku

Yoruba

Pronunciation

  • IPA(key): /ʃù.kù.ʃù.kù/

Ideophone

ṣùkùṣùkù

  1. (of a liquid) gargling
    Máa fi omi àti iyọ̀ yọnu ṣùkùṣùkù.Use salt and water to gargle.