ọmọ ile iwe

Yoruba

Etymology

From ọmọ (child) +‎ ilé-ìwé (school), literally School child.

Pronunciation

IPA(key): /ɔ̄.mɔ̃̄ ī.lé ì.wé/

Noun

ọmọ ilé ìwé

  1. student
    Synonym: akẹ́kọ̀ọ́