ọrọ aṣiri
Yoruba
Etymology
From ọ̀rọ̀ (“word”) + àṣírí (“secret”).
Pronunciation
- IPA(key): /ɔ̀.ɾɔ̀ à.ʃí.ɾí/
Noun
ọ̀rọ̀ àṣírí
- secret matter, confidential matter
- Ọ̀rọ̀ àṣírí ni mo sọ o, etí kẹta ò gbọ́dọ̀ gbọ́ ọ. ― I just told you a secret, a third ear must not hear it.