agọ ọlọpaa

Yoruba

Etymology

From àgọ́ (station, encampment) +‎ ọlọ́pàá (police)

Pronunciation

  • IPA(key): /à.ɡɔ́ ɔ̄.lɔ́.k͡pàá/

Noun

àgọ́ ọlọ́pàá

  1. police station
    Ìyá mi ti lọ sí àgọ́ ọlọ́pàá láti máa dá àwọn ìbéèrè kan lóhùnMy mother went to the police station to answer some questions