aibikita

Yoruba

Etymology

From àì- (negative nominalizing prefix) +‎ bìkítà (to care about).

Pronunciation

  • IPA(key): /à.ì.bì.kí.tà/

Noun

àìbìkítà

  1. carelessness; negligence; indifference; neglect
    Ìwà àìbìkítà ènìyàn lè fa ìjàǹbá iná lórí okoHuman carelessness can cause fires on farms