akete

Yoruba

Pronunciation

  • IPA(key): /à.ké.tē/

Noun

àkéte

  1. a traditional wooden bed
    Ọmọ ụmọlẹ̀ kẹ́ẹ̀ pọ̀nnọ̀, kọ́ gbé ọ tórí àkéte lọ
    The child of the deity that cannot be on the footpath, so they take it on the wooden bed and go
    (oríkì of an Èkìtì family from the town of Ìlárá-Mọ̀kín)
  2. hammock