alaamu
Yoruba
Etymology 1
Pronunciation
- IPA(key): /à.láà.mũ̀/
Noun
àláàmù
- alarm clock
- Synonym: wọnranran
- Synonym: ìdágìrì
Etymology 2
Pronunciation
- IPA(key): /ā.láà.mũ̀/
Noun
aláàmù
- lizard, gecko
- Synonyms: aláǹgbá, olódòǹgboro
- 2008 December 19, Yiwola Awoyale, Global Yoruba Lexical Database v. 1.0[1], number LDC2008L03, Philadelphia: Linguistic Data Consortium, , →ISBN:
- Gbogbo aláàmù l'ó danú délẹ̀, a kò mọ èyí tí inú ń run.
- All lizards lie down on their bellies, we do not know whose bellies ache (proverb on personal sorrow).