aladuugbo

Yoruba

Etymology

From oní- (one who has) +‎ àdúgbò (neighbourhood).

Pronunciation

  • IPA(key): /ā.lá.ꜜdú.ɡ͡bò/

Noun

aládùúgbò

  1. neighbour
    Synonym: ará àdúgbò