Yoruba
Etymology
Borrowed from English coffee.
Pronunciation
Noun
kọfí
- coffee
- mu kọfí ― to drink coffee
Nítorí kọfí mímu t'ó mu láràárọ̀, ó gbára lé kaféènì kí ó lè ṣe ohunkóhun.- Because he drinks coffee every morning, he relies on caffeine to do anything.