kọrin

See also: Appendix:Variations of "korin"

Yoruba

Alternative forms

  • كوَْرِن

Etymology

From kọ (to recite) +‎ orin (song)

Pronunciation

  • IPA(key): /kɔ̄.ɾĩ̄/

Verb

kọrin

  1. to sing
    Mò ń kọrin lọ́wọ́I am singing right now

Derived terms