olomele
Yoruba
Etymology
Pronunciation
- IPA(key): /ō.ló.mē.lē/
Noun
olómele
- (music) omele drummer
- Kò sẹ́ni tó mèdè àyàn bí ẹni tó gbé ọ̀pá ẹ̀ lọ́wọ́, olómele ló mọ ohun tí ó ń fi omele sọ.
- There's no one that knows the speech of a drum like the person who carries the drumstick in their hand, it's the omele drummer who knows what they are speaking through the drum
Derived terms
- olómele kì í sọ pé igi yóò dá lóde lọ́la