ainisuuru
Yoruba
Alternative forms
- اَاِنِسُاُرُ
Etymology
From àì- (“negative nominalizing prefix”) + ní (“to have”) + sùúrù (“patience”)
Pronunciation
- IPA(key): /à.ì.nĩ́.sùú.ɾù/
Noun
àìnísùúrù
- a lack of patience, impatience, restlessness
- Synonym: wàdùwàdù
- Àìnísùúrù ló pa á ― Impatience killed him
Derived terms
- aláìnísùúrù (“impatient person”)