asinwin

Yoruba

Alternative forms

  • ọsíún

Alternative forms

  • اَسِنوِن

Etymology

From a- (agent prefix) +‎ sínwín (to be insane)

Pronunciation

  • IPA(key): /ā.sĩ́.wĩ́/

Noun

asínwín

  1. lunatic, demented person, insane person
    Synonym: aṣiwèrè
    Má ṣe bí asínwín!Don't act like a lunatic!