eleredere
Yoruba
Etymology
Pronunciation
- IPA(key): /ē.lé.ɾē.dè.ɾē/
Noun
eléredère
- (Àkúrẹ́) perfect, beautiful; something perfectly shaped
- Kín bá ti mọ fọ̀, Ùgbèyìn nọ́n tị́ ị jọba, màá tètè yáyà. Màá mádé eléredère kọ̀n, dórí mi ooooo(oríkì of Odò-Ùgbèyìn, a historic neighborhood in the town of Ìlárá-Mọ̀kín)
- If I had known that it was in Ugbeyin that reign as king, I would have quickly went there. And I shall take a beautiful crown, and put it on my head