Yoruba
- ị̀yọ̀n lị́yọ̀n, ị̀yàn nị́yàn, ị̀yọ̀nnị́yọ̀n
Etymology
From ịyọ̀n (“far distance”) + ní + ị̀yọ̀n
Pronunciation
- IPA(key): /ɪ̀.jɔ̃̀ nɪ̃́.jɔ̃̀/
Noun
ị̀yọ̀n nị́yọ̀n
- (Ekiti) far distance; that which is far away
- Synonyms: ị̀yọ̀n, ọ̀nà-jíjìn
Ị̀yọ̀n nị́yọ̀n lulé rịn-ọn à?- Their house is far away
- (literally, “It is a far place that their house is located”)
Ị̀yọ̀n nị́yọ̀n ni mo ti rí aṣọ òfì rà, lọ́ọ̀ụ́rọ̀ kùtù lóòní- It was at a far place that I was able to buy asọ oke clothing, early today morning