ọrọ-ayalo
Yoruba
Etymology
From ọ̀rọ̀ (“word”) + àyálò (“borrowed”).
- àyálò from à- (“nominalizing prefix”) + yá (“to borrow”) + lò (“to use”), literally “that which is borrowed for use”.
Pronunciation
- IPA(key): /ɔ̀.ɾɔ̀.à.já.lò/
Noun
ọ̀rọ̀-àyálò
- loanword
- "Àdúrà" ni àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀-àyálò lédè Yorùbá ― "Àdúrà" is an example of a loanword in Yorùbá
Hyponyms
- ọ̀rọ̀-àfetíyá (“ear-loan”)
- ọ̀rọ̀-àfojúyá (“eye-loan”)