ogede

See also: ọgẹdẹ

Yoruba

Etymology 1

Pronunciation

  • IPA(key): /ò.ɡè.dè/

Noun

ògèdè

  1. incantation, gibberish, spell
    Synonyms: ọfọ̀, mádàáríkàn
    baba ń pògèdè sí ọgbẹ́ ejòThe elder was chanting an incantation on the snake bite
Derived terms

Etymology 2

Pronunciation

  • IPA(key): /ò.ɡè.dē/

Noun

ògède

  1. attic
    Synonym: àjà

Etymology 3

Pronunciation

  • IPA(key): /ò.ɡé.dé/

Noun

ògédé

  1. only, nothing else other than something
    ògédé iṣu nìkàn l'ó wà lọ́jàThe market only had yam, nothing else
  2. full, fullness
    ògédé àgálámọ̀ṣà ni gbogbo ọ̀rọ̀ọ rẹ̀His utterances fully consisted of inconsistencies