yooku
Yoruba
Alternative forms
- ìyókù, ìyòókù
Etymology
From èyí (“this”) + ti (“that”) + ó (“third person pronoun”) + kù (“to remain”), literally “That which remains”
Pronunciation
- IPA(key): /jòó.kù/
Noun
yòókù
- remainder, rest, others
- Synonym: ìyòókù
- Jẹ́ kí àwọn yòókù mọ̀ pé à ń bọ̀ láìpẹ́ ― Let the others know that we'll be there soon
Derived terms
- ìyòókù (“remainder, rest”)